Awon adigunjale pa awon osise Customs meji ni ilu Katsina.


Awon afurasi adigunjale kan ni ale ana pa awon omo egbe osise Customs ton soju ilu Katsina ni agbegbe Shargalle Dogonhawa ni ipinle Katsina. Awon ologbe meji lo se arinfesesi nigba ti awon adigunjale na sise won, ti won si yin ibon pa awon mejeji. Oruko awon ologbe mejejei yi ni CSC Maidamma Usman Yabo ati ASC Nuruddeen Babandi.
Awon agbofinro ti wa bere iwadi lori oro yi, won si ti gbe oku awon ologbe na lo si ile igboku si.

Comments