Awon agbenipa pa Oba kan ni ipinle Ondo.






Awon agbenipa kan ni iroyin fi to wa leti wipe won ti pa Oba Oba Patrick Fasinu olowo ti ilu Owo ni ipinle Ondo. Isele na waye ni ijoba ipinle Yewa South ni ojo kerindinlogbon osu keje.
Gege bi iwadi ti awon olopa se, won ni isele na sele nigba ti oba alayeluwa na n bo lati ipade awon lobaloba ni ipinle na. Awon agbenipa na da oko kabiyesi na duro, won wo jade, won si fi ake sa pa. Nigba ti won sa tan, won gbe oku re sinu oko re, won si da ina sun oko na pelu oku Oba na.
Awon agbofin ro ti bere iwadi to peye lori oro na, won si ti fi awako Oba na si atimole won.

Comments