Awon aworan nibi igbeyawo laarin omo Gomina Ibikunle Amosun ati Abike Dabiri.










Igbakji Aare Yemi Osibajo, Iyawo ati awon omo re, pelu awon omo Muhamodu Buhari lo peju si ibi ayeye igbeyawo awon omo Gomina Amosun ati Arabirin Abike Dabiri to waye ni ipinle Ogun ni ojo kejo osu yi. Opolopo awon eyan jankan-jankan lo peju sibi igbeyawo na.

Comments