Awon omo egbe okunkun Badoo to n' pa eyan ni ipinle Eko tun ti pa awon marun ninu idile kan. +18






Awon omo egbe okunkun Badoo lo tun lo pa awon molebi kan ni nkan bi ago meji oru ni ojo kokandinlogbon ni agbegbe Oke Ota ni Ibeshe, Ikorodu. Aro ojo keji ni awon ara-adugbo ri oku awon maraun ninu idile na. Awon agbofinro ti wa bere iwadi lori oro na, won si ti gbe oku awon ologbe na lo si ile igboku si ni ipinle Eko.

Comments