Ijoba ipinle Eko ti pase fun awon agbofinro lati bere si wo awon ile ti won ko si oju opopona ni agbegbe Obalende ni ipinle Eko. Isele na waye leyin osu mefa ti ijoba ipinle na so fun awon olugbe opopona na lati kuro ni ibe.
Ogbeni Olayinka Egbeyemi, eni to je
Chairman of the Lagos State Task Force Superintendent of Police lo so wipe awon ti kilo fun awon olugbe agbegbe na ni nkan bi wakati mejidinladota (48hrs) seyin lati kuro ni agbegbe na, sugbon won ko eti ikun si oro won.
Comments
Post a Comment