Omobirin Gomina ipinle Jigawa nigba kan ri ti ku.





Hajia Hadiza Sule Lamido omobirin keji Gomina ipinle Jigawa ni gba kan ri  Dr. Sule Lamido ti ku . O ku ni ile iwosan kan ni orilede India ni aro ojokokandinlogbon osu keje odun yi leyin aisan ranpe.
Adura wa ni wi pe ki Olorun te arabirin na si afefe ire. Amin.

Comments