Awon agbofinro ti ri odomode kunrin to sonu ni ilu Warri ni ipinle Eko.



Odomode kunrin omo odun merindinlogun  Ese Akiri to sonu ni No. 3 Odinabel Street, Orerokpe, ni ijoba ipinle Okpe ni ipinle Delta ni awon agbofinro ti ri ni ojo aje ni agbegbe  Ojodu Berger ni ipinle, Eko. Gege bi atejade ti awon agbofinro se , won ni awon ri omo na ton rin gbere-gbere kakiri ni agbegbe  Ojodu – Berger, Lagos. Nigba ti won fi oro wa odomode na lenu wo, o so wipe ohun ni wahala kan ni ile, ohun wa pinu lati tele ore ohun

Comments