Awon agbofinro ton soju ipinle Enugu lo dawo rogbodiyan duro ni agbegbe Ozalla ijoba ipinle Nkanu West ni ipinle Enugu. Iroyin fi to wa leti wipe awon Fulani daran-daran lo se ikolu si agbegbe Umane Ngene ti won si fi ada sa arakunrin kan ti oruko re n je Ndubueze Oboro.
Awon agbofinro ti bere iwadi lati mo awon amokunseka yi, won si ti pinu lati fi oju won ri mabo.
Awon tiwon fi ara pa ninu ikolu yi ni won ti gbe lo si ile iwosan.
Comments
Post a Comment