Awon Gomina lo se ipade pelu olori awon ajijagbara fun orilede Biafra Nnamdi Kanu.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Gomina ipinle Enugu Ifeanyi Ugwuanyi, Gomina ipinle Ebonyi Dave Umahi, Gomina ipinle Anambra loni lo se abewo pelu ogbeni Nnamdi Kanu ni ilu Enugu. Idi ti won fi se ipade yi lo je nkan ti won fi pamo fun gbogbo eyan.
Comments
Post a Comment