Awon omo egbe ASUU ko lati lo se ipade pelu ijoba apapo.

Awon agbagba ninu egbe Academic Staff Union of Universities loni ko lati lo se ipade pelu awon ijoba apapo. Gege bi atejade ti awon oniroyin Channels TV se, oga agba ajo ASUU Biodun Ogunyemi se atejade wipe  awon oni se ipade pelu awon asoju ijoba apapo.

Comments