Baba gbajugbaja odomode olorin African China ti ku.

Chinagorom Onuoha ti gbogbo eyan mo si  African China ni o se atejade yi baba ohun, Alagba Onuoha ti ku ni ogbon ojo osu kejo leyin to ba aisan jija kadi.
  Atejade ti odomodekunrin na se niyi ni ede geesi ;

'the man That God used to bring me into this world, My Hero, My mentor, Papa you tutored me on how to be a good father to my kids. Papa passed on today 30th august 2017….early hours of this morning R.I.P papa'.

Comments