Gbajugbaja oserekunrin Obi Madubogwu ti ku.

Gbajugbaja oserekurin Obi Madubogwu  eniti iwadi fi ye wa wipe o tin ba aisian ja fun bi odun melo kan ti ku . Adura wa ni wipe ki olorun te ologbe na si afefe ire. Amin.

Comments