Ijoba apapo ti fun awon osise ni isimi ni ojo kini ati ojo kerin osu kesan lati fi se ayeye odun Ileya.

Gege bi atejade ti minista fun eto abele ogbeni Abdulrahman Dambazau se, okede wipe ijoba apapo tipinu lati fun awon osise ni isimi olojo meji, eyi ti yo waye ni ojo kini ati ojo kerin osu kesan odun yi. Isimi yi ni yo waye lati se ayeye odun Ileya fun awon musulumi.

Comments