Ijoba apapo ti yan igbakeji Aare Yemi Osinbajo gege bi agbenuso laarin ijoba ati awon omo egbe ASUU.

Igbakeji Aare Yemi Osinbajo ni won ti yan gege bi oludari awon ti yo lo gbenuso fun ijoba nibi ipade lori eto idasele to waye ninu eto eko lati owo awon omo egbe ASUU. Minisita Chris Ngige lo se atejade yi leyin ipade Federal Executive Council meeting to waye lana ni ilu Abuja.

Atejade ti Minisita Chris Ngige se ni yi ni ede geesi;
“At council today, the Vice President has taken over some of the aspects of the negotiations and discussions. So, we are continuing the meeting in his office and when we finish meeting, we will get back to ASUU for another round of meeting and we are hopeful that we will be able to go to an appreciable extent to solve some of the outstanding issues that is preventing them from going back to work’’.

Comments