Ile ejo ijoba apapo to wa ni ipinle Eko ti sun igbejo ogbontarigi ajinigbe Chukwudumeme Onwuamadike eni ti gbogbo eyan mo si Evans si ojo karun osu kesan odun 2017.
Ojo kokandinlogbon osu yi lo ye ki ile ejo na da ejo arakunrin yi sugbon won sun igbejo na siwaju nitori iwadi awon olopa ton lo siwaju.
Ojo kokandinlogbon osu yi lo ye ki ile ejo na da ejo arakunrin yi sugbon won sun igbejo na siwaju nitori iwadi awon olopa ton lo siwaju.
Comments
Post a Comment