Arakunrin Salim ati Arabirin Zainab ti won se igbeyawo ni ojo kokandinlogun osu kejo ni igbeyawo won ti ja si ofo ni igba ti arabirin na fo sanle lojiji to si ku ni ojo kokandinlogbon osu yi.
Awon molebi ati ore awon mejeji ti wa bere sini petu si arakunrin na lokan.
Adura wa ni wipe ki Olorun foriji ologbe na, ko si fun oko na ni agbara lati le farada iku iyawo re. Amin.
Comments
Post a Comment