Ogbeni Mark Zuckerberg ati iyawo re Priscilla Chan ti bi omobirin lanti-lanti.

Alakoso ati oludari itakun ayelujara Facebook, ogbeni Mark Zukerberg ati iyawo re Priscilla Chan ti bi omobirin tuntun loni. Omobirin yi ni yo je omo keji ti awon toko-taya yi o bi.  August ni oruko ti won so omo na.
Mark lo se atejade ati afihan aworan yi lati fi idunu re han. Atejade na ni yi ni ede geesi;
'Childhood is magical. You only get to be a child once, so don't spend it worrying too much about the future. You've got us for that, and we'll do everything we possibly can to make sure the world is a better place for you and all children in your generation'.

Comments