Ogbeni Tony Nwoye lo jawe olubori gege bi oludije fun ipo Gomina ni abe egbe oloselu APC ni Ipinle Anambra.

Ogbeni Tony Nwoye  lo jawe olubori nibi eto idibo fun egbeoloselu APC fun ipo Gomina ipinle Anambra . Awon eyan 2146 ni o dibo fun ogbeni Tony Nwoye,ti awon 931 si dibo fun akegbe re Andy Uba.

Comments