Gege bi atejade ti arabirin Zainabu se lori ero ayelujara instagram, o so wipe looto ni igbeyawo ohun ati Ooni Adeyeye ti dopin. O so wipe ki eni kankan ma so oro odi si ohun latari isele to sele yi, wipe Olorun nikan lo le dajo.
Atejade to se ni yi ni ede geesi;
Comments
Post a Comment