Gege bi atejade ti omo egbe agbaboolu Super eagles Emmanuel Emenike se lori ero ayelujara facebook, ati afihan awon aworan, o so wipe inu ohun dun lati ki omo tuntun ti olorun fi da awon lola.
Atejade na ni yi ni ede geesi;
Emenike shared the photos on IG with the caption "Blessed and highly favored. Our princess is here. #daddyduties"
Comments
Post a Comment