Ogbeni Olufemi Onimole eni to je omo egbe ile igbimo asofin nigbakan ri ni to'n soju Ifako Ijaiye Federal Constituency ni odun1999 si 2003 labe egbe oloselu Alliance for Democracy (AD) ti ku. Iroyin fi to wa leti wipe ojo abameta ni ologbe olufemi je olorun ni ipe ni ile iwosan kan to wa ni ilu London.
Adura wa ni wipe ki Olorun fori ji ologbe na, ko si te si afefe ire amin.
Adura wa ni wipe ki Olorun fori ji ologbe na, ko si te si afefe ire amin.
Comments
Post a Comment