Omobirin Gomina ipinle Cross River nigbakan ri Xerona Duke ati oko afesona re Derin Phillips ti gbogbo eyan mo si DJ Caise ti setan lati gbe ara won ni iyawo.



Odomode kunrin na lo se afihan awon aworan yi lori ero ayelujara instagram.

Comments