Oni ni ojo ibi gbajugbaja oserebirin Jocelyn Dumas.


Gbajugbaja soro-soro ati oserebirin omo orilede Ghana arabirin Jocelyn Dumas lo se afihan awon aworan yi, to si se atejade kan lati se ayeye ayajo ojoibi re.
Atejade na ni yi ni ede geesi;
" You are a QUEEN never forget that. You are who God says you are; don't let the words or the opinions of others define you, and even though you have moments you feel like quitting, God said to hold on for His promises to you are #yay and #Amen.”

Comments