Oserebirin Mercy Johnson ati oko re Omoba Odi Okojie fi ife han si ara won lati se ayeye odun kefa igbeyawo won.





Awon ololufe mejeji yi ni lo se atejade lati ki ara won lori ero ayelujara  instagram lati fi ife won han si ara won, lati si se ayeye odun kefa ti won se igbeyawo.

Comments