Owo awon agbofinro ti ba awon odaran meji kan ti won man ta eya ara eyan fun ogun owo ni ipinle Niger. +18


Awon agbofinro ton soju ipinle Niger, mu awon odaran meji kan ni ojo kerindinlogbon, osu kejo odun yi fun esun agbenipa. Awon odaran meji yi ni won pa arakunrin kan ti oruko re nje Ogbeni Hassan Abubakar lati ijoba ipinle Bakajeba Paiko.
Awon odaran meji yi ti oruko won n je  Abdulrasheed Aminu omo odunmejilelogun lati ilu Lupa ati Ismaila Mohammed omo odunmetadinlogbon lati ilu makera ni won jewo wipe awon fi obe gba ori lorun Hassan ti awon si ni lokan lati fi se ogun owo.
Awon agbofinro ti mu awon odaran na, won si ti pinu lati gbe won lo si ile ejo.

Comments