Aare Buhari ti pada de Abuja lati ipade UN General Assembly ni ilu New York.



Aare Buhari ni irole oni ti pada de ilu Abuja leyin irinajoto rin lo si orilede America fun ipade elekejileladorin ti UN General Assembly to waye ni ilu New York.

Comments