Aburo Gomina ipinle Plateu, Solomon Dalung ti ku leyin aisan ranpe.

Ogbeni Wummen Bako Lalong eni to je aburo fun Gomina ipinle Pleateu ni iroyin fi to wa leti wipe o ti ku ni aro kutu-kutu oni. Gege bi atejade ti ikan ninu awon osise re Naandoet John se, o so wipe nkan bi osu kan ni arakunrin na tin ba aisan finra, sugbon oni ni aisan na papa gba emi okunrin na.
  Oluko ni Ogbeni Wummen Bako Lalong ni ile iwe giga ti  University of Jos ki olojo to de.
Adura wa ni wipe ki Olorun dari gbogbo ese ologbe na ji, ko si fun awon molebi re ni ore ofe lati le gba wipe boluwatife ni. Amin.

Comments