An wa omokunrin omodun meta kan!.

Omo odun meta kan ti oruko re n je Ibrahim ni awon obi re n wa ni agbegbe Epe ni ipinle Eko lana ni ojoketadinlogbon osu kesan odun yi. Eni keni to ba ba wa ri omona ko fi to awon agbofinro leti. Tabi ko kan si  @findmealert lori ero ayelujara Facebook.

Comments