Arakunrin kan omoodun merinlelogota kan ti oruko re nje Mammadu lo fo sanle lojiji to si ku ninu oja Jada ni ipinle Adamawa. Gege bi atejde ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe Ogbeni Mammadu, je omo bibi ilu Mubi ni ipinle na. Won so wipe lojiji ni arakunrin na daku, ti won si so wipe o ti ku leyin nkan bi wakati merin.
Won ti gbe oku arakunrin na lo si ite igbokusi ni ipinle na.
Comments
Post a Comment