Ayeye ojo ibi Tiwaloluwa, omo gbajugbaja alawada Seyi Law.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Tiwaloluwa Oluwademiladeola Chidera Aviella omobirin gbajugbaja alawada yo di omo odun kan ni ola, ojo kini osu kewa odun yi. Arakunrin na ati iyawo re ti wa bere ayeye ojo ibi lati fi se ayeye na.
Comments
Post a Comment