Gomina ipinle Eko, Akinwunmi Ambode loni lo se afihan awon ero amunawa fun awon olopa ati agbofinro. O se eyi lati je ki itesiwaju ba ise awon olopa na ninu fi opin si awon iwa ti to tona lawujo.
Oga olopa ton soju ipinle Eko ki Gomina na ku ise, o si dupe gidi-gidi lowo re.
Comments
Post a Comment