Gomina ipinle Osun fi idunu re han nigba to pade ogbontarigi agbaboolu alafesegba Ogbeni Nwakwo Kanu.


Gomina ipinle Osun Ogbeni Rauf Aregbesola se afihan aworan ati atejade kan lori ero ayelujara instagram lati fi idunu re han nigba to pade ogbontarigi agbaboolu alafesegba  Ogbeni Nwakwo Kanu.

Comments