Leyin gbogbo atotonu lori wipe awon omo iya meji ati ibeji olorin Psquare ti fe tuka, Peter lo se afihan aworan yi lati fi han nibi ti ikeji re ati egbon won jude ti fe ba ohun ja ijakadi.
Ibanuje nla lo je fun gbogbo awon ololufe won nigba ti aworan yi jade.
Comments
Post a Comment