Ijoba apapo ti yan ojo keji osu kewa (Oct 2nd) gege bi ojo isimi lati fi se ayeye odun ketadinlogota ti orilede Nigeria.

Gege bi atejade ti ogbeni Lt Gen. Abdulrahman Dambazau (retd.) se, o fi han wipe ijoba apapo ti mu ojo keji osu kewa odun yi lati fi se ayeye odun ketadinlogota ti orilede Nigeria.
   Ojo isimi ni ojo na o je fun awon osise ijoba ati aladani lapapo.

Comments