Jude Okoye ati iyawo re ti bi omobirin lanti-lanti.





Odomode onisowo ati olorin Jude Okoye loni lo se afihan awon aworan yi, to si se atejade si lati dupe lowo Olorun fun ore ofe to fun ohun ati iyawo re lati bi omobirin lanti-lanti kan loni.
Eku orire o.

Comments