Rogbodiyan ti be sile ni ilu Kogi laarin awon Akeko ati awon awako oko ajagbe Dangote to pa awon akeko marun kan ni opopona Lokoja si Abuja.. +18
Awon akeko ipinle Kogi ti bere iwode ati ifehunu han ni oju opopona lokoja si Kogi. Eyi waye nigba ti oko ajagbe Dangote kan gba awon eyan marun ati akeko ile iwe giga na. Awon akeko na nigba ti won ba awon oniroyin soro so wipe ki se alakoko ti iru isele buruku yi yo sele.
Opolopo Dukia ni awon akeko na ti baje, ti won si ti gbe oku awon to so emi won nu ninu ijamba oko na lo si ite igboku si to wa ni ipinle na.
Comments
Post a Comment