Arabirin kan ti ko lati ni ade ori nitori pe ko fe kuro ni Lekki. lol O ga o.

Gege bi atejade ti arabirin kan ti oruko re nje Poison Ivy se lori ero ayelujara twitter, o so wipe kaka ki ohun kuro ni agbegbe Lekki ni ipinle Eko, ohun o ya ni se igbeyawo.   eleyi ga ju.

Comments