Arabirin Gaje Zubairu omo odun mejidinlogoji to bi omo iberin ni ipinle Katsina ni ojo kerinlelogun osu kewa ti jade laye. Iroyin fi to wa leti wipe awon ailera to so mo ise abe lo fa sababi iku arabirin na. Oniwosan agba ti ile iwosan General Hospital, Malumfashi, Katsina Dr . AbdulHamed Abdullahi, so wipe ago mokanla aro ni arabirin na jade laye.
Awon molebi arabirin na si ti se tan lati lo sin arabirin na si ilu re to wa ni Gora Dansaka gege bi ilana musulumi.
Awon molebi arabirin na si ti se tan lati lo sin arabirin na si ilu re to wa ni Gora Dansaka gege bi ilana musulumi.
Comments
Post a Comment