Awon aworan ipalemo fun igbeyawo gbajugbaja odomode olorin Oritsefemi ati iyawo afesona re Nabila.




Awon ololufe mejeji yi lo se afihan awon aworan yi lati fi ife won han, ki won si fi mura sile fun ayeye igbeyawo won ton bo lona ni ojo karundinlogbon osu kokanla odun yi ni ipinle Eko.

Comments