Awon aworan nibi ayeye ikomo omobirin Gomina Abiola Ajimobi.






Jibola, omobirin Gomina ipinle Oyo Abiola Ajimobi lo ti setan lati se ikomo ati afihan omo re. Jibola ati oko re Ayokunle Ajayi ni ti won se igbeyawo ni odun 2015 ni omo eleyi o je omo eleketa ti won o bi. Idunu ati ayo ni awon lokolaya na ya awon aworan na.  Eku orire o.

Comments