Awon eso Aare Buhari ko lati je ki Saraki ati Dogara ri Aare loni, ni ibudo Aare.

Gege bi atejade ti iwe iroyin Punch se loni, won so wipe awon eso Aare Buhari ko lati je ki Saraki ati Dogara yoju si Aare nigbati won lo se abewo si ni ibudo Aare, lati le so asoyepo lori eto  2018 appropriation bill. Awon ti oro na se oju won nigba ti won ba awon oniroyin soro so wipe ibinu ni awon adari mejeji yi fi kuro ni ibudo Aare na ni osan oni.

Comments