Awon odomodebirin meji tegbon-taburo kan ti oruko won nje Peace ati Jennifer John ni iroyin fi to wa leti wipe won ti sonu ni ipinle Bayelsa lati ojo kini osu kewa odun yi. Omo odun mejila ati merinla ni awon tegbon-taburo na. Ti enikeni ba ko firi awon odomode birin yi, ki won fi to awon agbofinro le'ti abi ki won pe awon ero ibara eni soro yi 0816-303-2098 abi Royal FM 95.5 0818-724-9744

Comments
Post a Comment