Awon omo ologun Nigeria pa ikan ninu awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ni ipinle Borno.

Awon omo egbe ologun 5 Brigade Garrison, 8 Division Nigerian Army, Operation LAFIYA DOLE, ti orilede Nigeria ti pa ikan ninu awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ni bi to tin gbiyanju lati yin ado oloro ni ojo kokandinlogbon osu kewa odun yi, ni agbegbe Aisaram, ni ijoba ipinle Gubio, ni ipinle Borno. Opolopo awon ohun nkan ija oloro bi ibon, ada, ake, obe pelu esin meji ati egberun meje naira ni won ba lowo arakunrin na.

Comments