Aworan Yemi Osinbajo,Ike Ekweremadu ati Yakubu Dogara nibi ipade adura fun orilede to waye ni aro kutu-kutu oni.




Igbakeji Aare Yemi Osinbajo, Alukoro ile igbimo asofin Yakubu Dogara ati igbakeji Aare ile igbimo asofin Ike Ekweremadu ati awon omoleyin Kristeni peju sibi ipade elekejo ti adura fun orilede to waye ni aro oni ojo kerindinlogbon osu kewa ni ilu Abuja.

Comments