O ma se o, Akeko ile iwe giga Auchi Polytechnic kan ku ninu ijamba oko leyin ojokan to keko jade.





Rog Royal, omo odun merinlelogun kan ati akeko jade ile iwe giga Auchi Polytechnic kan so emi re nu ninu ijamba oko kan to waye ni opopona Edo si Benin ni ose to koja, leyin ayeye ikeko jade omo na. Ibanuje nla lo je fun awon molebi omo na nigba ti won gbo isele kayefi na. Opolopo awon ore ati ololufe omo na ti se atejade lati ki arakunrin na wipe odigba o se.

Atejade ti ore re  Oluwa Prince se niyi ni ede geesi;
'It's still a shock to me that my friend rog is dead what a big lost to the department of electrical/electronics engineering a day after signing out... RIP it's rog Itz Rog Royal forever in our heart.. Sleep on SEES MAN'

Comments