O ma se o! Baba gbajugbaja oserebirin Mercy Aigbe ti ku.


Oserebirin Mercy Aigbe lo se afihan aworan ati atejade kan lori ero ayelujara instagram re loni, lati se odigba ose fun baba re to sese ku.   Adura wa ni wipe ki Olorun fi oriji baba na. Amin.

Comments