Aare Buhari lo'ni ojo aje, fi inu didun ati oyaya ki oga agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Tinubu kabo si ibudo Aare to wan ni Aso Rock ni ilu Abuja. Awon adari mejeji yi ni won jo se ipade fun nkan bi wakati melo kan ti won si fi oro jomitoro oro.
Idi ti ipade yi fi waye lo je kayefi fun gbogbo awon oni iwe iroyin.
Comments
Post a Comment