Oserebirin Ifunanya Igwe ti bi omobirin tuntun jojolo kan.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Oserebirin Ifunaya Igwe ati oko re Mike Ukpabia ti bi omobirin tuntun jojolo kan ti won so oruko re ni Michelle. Omobirin yi ni yo je omo won elekeji ti won o bi leyin odun kan ti won se igbeyawo. Eku orire o.
Comments
Post a Comment