Won ti fi oserebirin Tonto Dikeh je oye 'Adadioranma of Nollywood'. lo'ni.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Oserebirin Tonto Dikeh loni se afihan awon aworan yi lori ero ayelujara instagram re lati fi dupe lowo Olorun ati awon Ololufe re fun oye tuntun ti won fun gege bi 'Adadioranma of Nollywood'.
Comments
Post a Comment