Aare Buhari ki alaga egbe oloselu APC John Odigie-Oyegun ku araferakun lori bi Atiku Abubakar se fi egbe oloselu na sile.
Ni bi ipade to waye laarin Aare Buhari ati awon to yan fun eto National minimum wage committe, Aare Buhari ki alaga egbe oloselu APC ati gbogbo awon omo egbe oloselu na lapapo ku araferakun fun ti ikan ninu awon agba egbe oloselu na to fi egbe na sile.
Bo ti le je wipe Aare na o so oruko eni na ni pato, oye ye wa wipe Atiku Abubakar ni oro na ba wi.
Bo ti le je wipe Aare na o so oruko eni na ni pato, oye ye wa wipe Atiku Abubakar ni oro na ba wi.
Comments
Post a Comment